ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 32:21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  21 Wọ́n ti fi ohun tí kì í ṣe ọlọ́run+ mú mi bínú;*

      Wọ́n ti fi àwọn òrìṣà+ wọn tí kò ní láárí múnú bí mi.

      Torí náà, màá fi àwọn tí kì í ṣe èèyàn+ mú kí wọ́n jowú;

      Màá fi orílẹ̀-èdè òmùgọ̀+ mú wọn bínú.

  • 1 Sámúẹ́lì 12:21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 Ẹ má ṣe lọ máa tẹ̀ lé àwọn ohun asán*+ tí kò ṣàǹfààní,+ tí kò sì lè gbani, nítorí pé asán* ni wọ́n jẹ́.

  • 2 Àwọn Ọba 17:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Wọ́n ń pa àwọn ìlànà rẹ̀ tì àti májẹ̀mú+ rẹ̀ tó bá àwọn baba ńlá wọn dá àti àwọn ìránnilétí rẹ̀ tó fi kìlọ̀ fún wọn,+ wọ́n ń sin àwọn òrìṣà asán,+ àwọn fúnra wọn sì di asán,+ torí wọ́n ń fara wé àwọn orílẹ̀-èdè tó yí wọn ká tí Jèhófà pàṣẹ fún wọn pé kí wọ́n má ṣe fara wé.+

  • Àìsáyà 41:29
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 29 Wò ó! Gbogbo wọn jẹ́ ẹ̀tàn.*

      Iṣẹ́ wọn kò já mọ́ nǹkan kan.

      Afẹ́fẹ́ lásán àti ohun tí kò sí rárá ni àwọn ère onírin* wọn.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́