ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Sámúẹ́lì 7:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Ní báyìí, sọ fún Dáfídì ìránṣẹ́ mi pé, ‘Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí: “Mo mú ọ láti ibi ìjẹko, pé kí o má da agbo ẹran mọ́,+ kí o lè wá di aṣáájú àwọn èèyàn mi Ísírẹ́lì.+

  • 2 Sámúẹ́lì 7:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Nígbà tí o bá kú,+ tí o sì sinmi pẹ̀lú àwọn baba ńlá rẹ, nígbà náà, màá gbé ọmọ* rẹ dìde lẹ́yìn rẹ, ọmọ ìwọ fúnra rẹ,* màá sì fìdí ìjọba rẹ̀ múlẹ̀.+

  • 1 Kíróníkà 29:23
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 23 Sólómọ́nì jókòó sórí ìtẹ́ Jèhófà+ gẹ́gẹ́ bí ọba ní ipò Dáfídì bàbá rẹ̀, ó ṣàṣeyọrí, gbogbo àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sì ń ṣègbọràn sí i.

  • 2 Kíróníkà 1:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 1 Sólómọ́nì ọmọ Dáfídì ń lágbára sí i nínú ìjọba rẹ̀, Jèhófà Ọlọ́run rẹ̀ wà pẹ̀lú rẹ̀, ó sì sọ ọ́ di ẹni ńlá tó ta yọ.+

  • Sáàmù 89:36, 37
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 36 Àwọn ọmọ* rẹ̀ yóò wà títí láé;+

      Ìtẹ́ rẹ̀ yóò wà títí lọ bí oòrùn níwájú mi.+

      37 Yóò fìdí múlẹ̀ títí láé bí òṣùpá

      Bí ẹlẹ́rìí tó ṣeé gbára lé ní ojú ọ̀run.” (Sélà)

  • Sáàmù 132:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Tí àwọn ọmọ rẹ bá pa májẹ̀mú mi mọ́

      Àti àwọn ìránnilétí mi tí mo kọ́ wọn,+

      Àwọn ọmọ tiwọn náà

      Yóò jókòó sórí ìtẹ́ rẹ títí láé.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́