-
2 Kíróníkà 19:3, 4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Síbẹ̀, àwọn ohun rere kan wà tí a rí nínú rẹ,+ nítorí o ti mú àwọn òpó òrìṣà* kúrò ní ilẹ̀ yìí, o sì ti múra ọkàn rẹ sílẹ̀* láti wá Ọlọ́run tòótọ́.”+
4 Jèhóṣáfátì ń gbé ní Jerúsálẹ́mù, ó sì tún jáde lọ sáàárín àwọn èèyàn náà láti Bíá-ṣébà dé agbègbè olókè Éfúrémù,+ kó lè mú wọn pa dà sọ́dọ̀ Jèhófà Ọlọ́run àwọn baba ńlá wọn.+
-