ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Kíróníkà 15:16, 17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Dáfídì wá sọ fún àwọn olórí ọmọ Léfì pé kí wọ́n yan àwọn arákùnrin wọn tó jẹ́ akọrin láti máa fi ayọ̀ kọrin, kí wọ́n máa lo àwọn ohun ìkọrin, ìyẹn àwọn ohun ìkọrin olókùn tín-ín-rín àti háàpù+ pẹ̀lú síńbálì.*+

      17 Torí náà, àwọn ọmọ Léfì yan Hémánì+ ọmọ Jóẹ́lì, lára àwọn arákùnrin rẹ̀, wọ́n yan Ásáfù+ ọmọ Berekáyà, lára àwọn ọmọ Mérárì tí wọ́n jẹ́ arákùnrin wọn, wọ́n yan Étánì+ ọmọ Kuṣáyà.

  • Nehemáyà 11:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Àwọn tó tẹ̀ lé e yìí ni àwọn olórí ìpínlẹ̀* tí wọ́n ń gbé ní Jerúsálẹ́mù. (Ìyókù àwọn tó wà ní Ísírẹ́lì, àwọn àlùfáà, àwọn ọmọ Léfì, àwọn ìránṣẹ́ tẹ́ńpìlì*+ àti àwọn ọmọ àwọn ìránṣẹ́ Sólómọ́nì,+ wọ́n ń gbé ní àwọn ìlú míì ní Júdà, kálukú sì ń gbé lórí ohun ìní rẹ̀ nínú ìlú rẹ̀.+

  • Nehemáyà 11:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 àti Matanáyà,+ ọmọ Míkà ọmọ Sábídì ọmọ Ásáfù,+ olùdarí orin, tó máa ń gbé orin ìyìn nígbà àdúrà+ àti Bakibúkáyà tó jẹ́ èkejì nínú àwọn arákùnrin rẹ̀ pẹ̀lú Ábídà ọmọ Ṣámúà ọmọ Gálálì ọmọ Jédútúnì.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́