-
Nehemáyà 7:46-56Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
46 Àwọn ìránṣẹ́ tẹ́ńpìlì* nìyí:+ àwọn ọmọ Síhà, àwọn ọmọ Hásúfà, àwọn ọmọ Tábáótì, 47 àwọn ọmọ Kérósì, àwọn ọmọ Síà, àwọn ọmọ Pádónì, 48 àwọn ọmọ Lébánà, àwọn ọmọ Hágábà, àwọn ọmọ Sálímáì, 49 àwọn ọmọ Hánánì, àwọn ọmọ Gídélì, àwọn ọmọ Gáhárì, 50 àwọn ọmọ Reáyà, àwọn ọmọ Résínì, àwọn ọmọ Nékódà, 51 àwọn ọmọ Gásámù, àwọn ọmọ Úúsà, àwọn ọmọ Páséà, 52 àwọn ọmọ Bésáì, àwọn ọmọ Méúnímù, àwọn ọmọ Néfúṣésímù, 53 àwọn ọmọ Bákíbúkì, àwọn ọmọ Hákúfà, àwọn ọmọ Háhúrì, 54 àwọn ọmọ Básílítì, àwọn ọmọ Méhídà, àwọn ọmọ Háṣà, 55 àwọn ọmọ Bákósì, àwọn ọmọ Sísérà, àwọn ọmọ Téémà, 56 àwọn ọmọ Nesáyà àti àwọn ọmọ Hátífà.
-