-
Nehemáyà 7:6, 7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Àwọn yìí ni àwọn èèyàn ìpínlẹ̀* tí wọ́n pa dà lára àwọn tó wà nígbèkùn, àwọn tí Nebukadinésárì+ ọba Bábílónì kó lọ sí ìgbèkùn,+ àmọ́ tí wọ́n pa dà sí Jerúsálẹ́mù àti Júdà nígbà tó yá, kálukú pa dà sí ìlú rẹ̀,+ 7 àwọn tí wọ́n tẹ̀ lé ni Serubábélì,+ Jéṣúà,+ Nehemáyà, Asaráyà, Raamáyà, Náhámánì, Módékáì, Bílíṣánì, Mísípérétì, Bígífáì, Néhúmù àti Báánà.
Iye àwọn ọkùnrin tí wọ́n jẹ́ ọmọ Ísírẹ́lì nìyí:+
-