ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Àwọn Ọba 14:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Jèhóáṣì ọba Ísírẹ́lì mú Amasááyà ọba Júdà, ọmọ Jèhóáṣì ọmọ Ahasáyà, ní Bẹti-ṣémẹ́ṣì. Lẹ́yìn náà, wọ́n wá sí Jerúsálẹ́mù, ó sì ṣe àlàfo sára ògiri Jerúsálẹ́mù láti Ẹnubodè Éfúrémù+ títí dé Ẹnubodè Igun,+ ọgọ́rùn-ún mẹ́rin (400) ìgbọ̀nwọ́.*

  • Nehemáyà 12:38, 39
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 38 Ẹgbẹ́ akọrin ọpẹ́ kejì gba òdìkejì* lọ, èmi àti ìdajì àwọn èèyàn náà sì tẹ̀ lé wọn, lórí ògiri lókè Ilé Gogoro Ààrò+ títí dé orí Ògiri Fífẹ̀+ 39 àti lókè Ẹnubodè Éfúrémù+ títí dé Ẹnubodè Ìlú Àtijọ́+ àti títí dé Ẹnubodè Ẹja,+ Ilé Gogoro Hánánélì,+ Ilé Gogoro Méà àti títí dé Ẹnubodè Àgùntàn;+ wọ́n sì dúró ní Ẹnubodè Ẹ̀ṣọ́.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́