Ẹ́sírà 8:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Àwọn olórí agbo ilé àti àkọsílẹ̀ orúkọ ìdílé àwọn tó tẹ̀ lé mi jáde kúrò ní Bábílónì nígbà ìjọba Ọba Atasásítà nìyí:+ 2 Gẹ́ṣómù, látinú àwọn ọmọ Fíníhásì;+ Dáníẹ́lì, látinú àwọn ọmọ Ítámárì;+ Hátúṣì, látinú àwọn ọmọ Dáfídì;
8 Àwọn olórí agbo ilé àti àkọsílẹ̀ orúkọ ìdílé àwọn tó tẹ̀ lé mi jáde kúrò ní Bábílónì nígbà ìjọba Ọba Atasásítà nìyí:+ 2 Gẹ́ṣómù, látinú àwọn ọmọ Fíníhásì;+ Dáníẹ́lì, látinú àwọn ọmọ Ítámárì;+ Hátúṣì, látinú àwọn ọmọ Dáfídì;