Ẹ́sítà 3:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Lẹ́yìn èyí, Ọba Ahasuérúsì gbé Hámánì+ ọmọ Hamédátà ọmọ Ágágì+ ga, ó sì gbé ìtẹ́ rẹ̀ ga ju ti gbogbo àwọn ìjòyè yòókù tí wọ́n jọ wà.+ Ẹ́sítà 3:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ọba wá bọ́ òrùka àṣẹ+ ọwọ́ rẹ̀, ó sì fún Hámánì + ọmọ Hamédátà ọmọ Ágágì,+ ẹni tó jẹ́ ọ̀tá àwọn Júù.
3 Lẹ́yìn èyí, Ọba Ahasuérúsì gbé Hámánì+ ọmọ Hamédátà ọmọ Ágágì+ ga, ó sì gbé ìtẹ́ rẹ̀ ga ju ti gbogbo àwọn ìjòyè yòókù tí wọ́n jọ wà.+
10 Ọba wá bọ́ òrùka àṣẹ+ ọwọ́ rẹ̀, ó sì fún Hámánì + ọmọ Hamédátà ọmọ Ágágì,+ ẹni tó jẹ́ ọ̀tá àwọn Júù.