Jóòbù 16:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Wọ́n ti la ẹnu wọn gbàù sí mi,+Tẹ̀gàntẹ̀gàn ni wọ́n sì gbá mi ní ẹ̀rẹ̀kẹ́,Wọ́n kóra jọ rẹpẹtẹ láti ta kò mí.+ Jóòbù 16:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Àwọn ọ̀rẹ́ mi fi mí ṣe ẹlẹ́yà,+Bí mo ṣe ń da omi lójú sí Ọlọ́run.*+ Jóòbù 17:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Àwọn tó ń fini ṣe yẹ̀yẹ́ yí mi ká,+Àfi kí ojú mi máa wo* ìwà ọ̀tẹ̀ wọn. Hébérù 11:36 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 36 Àní, àdánwò tí àwọn míì kojú ni pé wọ́n fi wọ́n ṣẹlẹ́yà, wọ́n sì nà wọ́n lẹ́gba, kódà ó jùyẹn lọ, wọ́n fi ṣẹkẹ́ṣẹkẹ̀ dè wọ́n,+ wọ́n sì fi wọ́n sẹ́wọ̀n.+
10 Wọ́n ti la ẹnu wọn gbàù sí mi,+Tẹ̀gàntẹ̀gàn ni wọ́n sì gbá mi ní ẹ̀rẹ̀kẹ́,Wọ́n kóra jọ rẹpẹtẹ láti ta kò mí.+
36 Àní, àdánwò tí àwọn míì kojú ni pé wọ́n fi wọ́n ṣẹlẹ́yà, wọ́n sì nà wọ́n lẹ́gba, kódà ó jùyẹn lọ, wọ́n fi ṣẹkẹ́ṣẹkẹ̀ dè wọ́n,+ wọ́n sì fi wọ́n sẹ́wọ̀n.+