- 
	                        
            
            Sáàmù 25:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        Má ṣe jẹ́ kí àwọn ọ̀tá mi yọ̀ mí.+ 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Jeremáyà 17:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        18 Jẹ́ kí ojú ti àwọn tó ń ṣe inúnibíni sí mi,+ Àmọ́ má ṣe jẹ́ kí ojú tì mí. Jẹ́ kí jìnnìjìnnì bá wọn, Àmọ́ má ṣe jẹ́ kí jìnnìjìnnì bá mi. 
 
-