Jeremáyà 15:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ìwọ fúnra rẹ mọ̀, Jèhófà,Rántí mi kí o sì kíyè sí mi. Gbẹ̀san mi lára àwọn tó ń ṣe inúnibíni sí mi.+ Má ṣe jẹ́ kí n ṣègbé* torí o kì í tètè bínú. O ṣáà mọ̀ pé nítorí rẹ ni mo ṣe ń fara da ẹ̀gàn yìí.+ Jeremáyà 20:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ṣùgbọ́n Jèhófà wà pẹ̀lú mi bíi jagunjagun tó ń bani lẹ́rù.+ Ìdí nìyẹn tí àwọn tó ń ṣe inúnibíni sí mi á fi fẹsẹ̀ kọ, wọn ò sì ní borí.+ Ojú á tì wọ́n wẹ̀lẹ̀mù, torí pé wọn ò ní ṣàṣeyọrí. Wọ́n á tẹ́ títí láé, ẹ̀tẹ́ wọn ò sì ní ṣeé gbàgbé.+
15 Ìwọ fúnra rẹ mọ̀, Jèhófà,Rántí mi kí o sì kíyè sí mi. Gbẹ̀san mi lára àwọn tó ń ṣe inúnibíni sí mi.+ Má ṣe jẹ́ kí n ṣègbé* torí o kì í tètè bínú. O ṣáà mọ̀ pé nítorí rẹ ni mo ṣe ń fara da ẹ̀gàn yìí.+
11 Ṣùgbọ́n Jèhófà wà pẹ̀lú mi bíi jagunjagun tó ń bani lẹ́rù.+ Ìdí nìyẹn tí àwọn tó ń ṣe inúnibíni sí mi á fi fẹsẹ̀ kọ, wọn ò sì ní borí.+ Ojú á tì wọ́n wẹ̀lẹ̀mù, torí pé wọn ò ní ṣàṣeyọrí. Wọ́n á tẹ́ títí láé, ẹ̀tẹ́ wọn ò sì ní ṣeé gbàgbé.+