Jeremáyà 51:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 “Ìwọ obìnrin tó ń gbé lórí omi púpọ̀,+Tí o ní ìṣúra tó pọ̀ rẹpẹtẹ,+Òpin rẹ ti dé, o ti dé òpin* èrè tí ò ń jẹ.+ Ìsíkíẹ́lì 3:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Mo wá lọ sọ́dọ̀ àwọn tó wà ní ìgbèkùn ní Tẹli-ábíbù, tí wọ́n ń gbé lẹ́bàá odò Kébárì,+ mo sì dúró síbi tí wọ́n ń gbé; mò ń wò suu,+ mo wà lọ́dọ̀ wọn fún ọjọ́ méje. Dáníẹ́lì 10:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ní ọjọ́ kẹrìnlélógún, oṣù kìíní, nígbà tí mo wà létí odò ńlá náà, ìyẹn Tígírísì,*+
13 “Ìwọ obìnrin tó ń gbé lórí omi púpọ̀,+Tí o ní ìṣúra tó pọ̀ rẹpẹtẹ,+Òpin rẹ ti dé, o ti dé òpin* èrè tí ò ń jẹ.+
15 Mo wá lọ sọ́dọ̀ àwọn tó wà ní ìgbèkùn ní Tẹli-ábíbù, tí wọ́n ń gbé lẹ́bàá odò Kébárì,+ mo sì dúró síbi tí wọ́n ń gbé; mò ń wò suu,+ mo wà lọ́dọ̀ wọn fún ọjọ́ méje.