Léfítíkù 18:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Kí ẹ máa pa àwọn àṣẹ mi àti àwọn ìdájọ́ mi mọ́; yóò mú kí ẹnikẹ́ni tó bá ń pa á mọ́ wà láàyè.+ Èmi ni Jèhófà. Diutarónómì 5:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 “‘Bọlá fún bàbá rẹ àti ìyá rẹ,+ bí Jèhófà Ọlọ́run rẹ ṣe pa á láṣẹ fún ọ gẹ́lẹ́, kí ẹ̀mí rẹ lè gùn, kí nǹkan sì lè máa lọ dáadáa fún ọ lórí ilẹ̀ tí Jèhófà Ọlọ́run rẹ máa fún ọ.+ Àìsáyà 55:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ẹ dẹ etí yín sílẹ̀, kí ẹ sì wá sọ́dọ̀ mi.+ Ẹ fetí sílẹ̀, ẹ* ó sì máa wà láàyè nìṣó,Ó sì dájú pé màá bá yín dá májẹ̀mú tó máa wà títí láé+Bí mo ṣe fi ìfẹ́ tí kì í yẹ̀, tó jẹ́ òótọ́,* hàn sí Dáfídì.+ Jòhánù 12:50 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 50 Mo sì mọ̀ pé àṣẹ rẹ̀ túmọ̀ sí ìyè àìnípẹ̀kun.+ Torí náà, ohunkóhun tí mo bá sọ, bí Baba ṣe sọ fún mi gẹ́lẹ́ ni mo sọ ọ́.”+
5 Kí ẹ máa pa àwọn àṣẹ mi àti àwọn ìdájọ́ mi mọ́; yóò mú kí ẹnikẹ́ni tó bá ń pa á mọ́ wà láàyè.+ Èmi ni Jèhófà.
16 “‘Bọlá fún bàbá rẹ àti ìyá rẹ,+ bí Jèhófà Ọlọ́run rẹ ṣe pa á láṣẹ fún ọ gẹ́lẹ́, kí ẹ̀mí rẹ lè gùn, kí nǹkan sì lè máa lọ dáadáa fún ọ lórí ilẹ̀ tí Jèhófà Ọlọ́run rẹ máa fún ọ.+
3 Ẹ dẹ etí yín sílẹ̀, kí ẹ sì wá sọ́dọ̀ mi.+ Ẹ fetí sílẹ̀, ẹ* ó sì máa wà láàyè nìṣó,Ó sì dájú pé màá bá yín dá májẹ̀mú tó máa wà títí láé+Bí mo ṣe fi ìfẹ́ tí kì í yẹ̀, tó jẹ́ òótọ́,* hàn sí Dáfídì.+
50 Mo sì mọ̀ pé àṣẹ rẹ̀ túmọ̀ sí ìyè àìnípẹ̀kun.+ Torí náà, ohunkóhun tí mo bá sọ, bí Baba ṣe sọ fún mi gẹ́lẹ́ ni mo sọ ọ́.”+