Àìsáyà 42:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 42 Wò ó! Ìránṣẹ́ mi,+ tí mò ń tì lẹ́yìn! Àyànfẹ́ mi,+ ẹni tí mo* tẹ́wọ́ gbà!+ Mo ti fi ẹ̀mí mi sínú rẹ̀;+Ó máa mú ìdájọ́ òdodo wá fún àwọn orílẹ̀-èdè.+ Mátíù 3:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Wò ó! Ohùn kan tún dún láti ọ̀run+ pé: “Èyí ni Ọmọ mi,+ àyànfẹ́, ẹni tí mo ti tẹ́wọ́ gbà.”+
42 Wò ó! Ìránṣẹ́ mi,+ tí mò ń tì lẹ́yìn! Àyànfẹ́ mi,+ ẹni tí mo* tẹ́wọ́ gbà!+ Mo ti fi ẹ̀mí mi sínú rẹ̀;+Ó máa mú ìdájọ́ òdodo wá fún àwọn orílẹ̀-èdè.+