Òwe 22:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Tọ́ ọmọdé* ní ọ̀nà tó yẹ kó tọ̀;+Kódà tó bá dàgbà, kò ní kúrò nínú rẹ̀.+ Òwe 22:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ọkàn ọmọdé* ni ìwà òmùgọ̀ dì sí,+Àmọ́ ọ̀pá ìbáwí yóò mú un jìnnà sí i.+ Òwe 23:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Má fawọ́ ìbáwí sẹ́yìn fún ọmọdé.*+ Tí o bá fi ọ̀pá nà án, kò ní kú. Éfésù 6:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ẹ̀yin bàbá, ẹ má ṣe máa mú àwọn ọmọ yín bínú,+ kàkà bẹ́ẹ̀, ẹ máa tọ́ wọn dàgbà nínú ìbáwí+ àti ìmọ̀ràn* Jèhófà.*+
4 Ẹ̀yin bàbá, ẹ má ṣe máa mú àwọn ọmọ yín bínú,+ kàkà bẹ́ẹ̀, ẹ máa tọ́ wọn dàgbà nínú ìbáwí+ àti ìmọ̀ràn* Jèhófà.*+