-
Sáàmù 64:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Dáàbò bò mí lọ́wọ́ ohun tí àwọn ẹni ibi ń gbèrò ní ìkọ̀kọ̀,+
Lọ́wọ́ àwùjọ àwọn aṣebi.
-
-
Sáàmù 64:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Ahọ́n àwọn fúnra wọn yóò mú kí wọ́n ṣubú;+
Gbogbo àwọn tó ń wò wọ́n yóò mi orí.
-
-
Òwe 14:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Pàṣán ìgbéraga wà ní ẹnu òmùgọ̀,
Àmọ́ ètè àwọn ọlọ́gbọ́n yóò dáàbò bò wọ́n.
-