1 Sámúẹ́lì 18:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Dáfídì ń ṣàṣeyọrí*+ nínú gbogbo ohun tó ń ṣe, Jèhófà sì wà pẹ̀lú rẹ̀.+ Òwe 3:32, 33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Nítorí Jèhófà kórìíra oníbékebèke,+Ṣùgbọ́n àwọn adúróṣinṣin ni ọ̀rẹ́ Rẹ̀ tímọ́tímọ́.+ 33 Ègún Jèhófà wà lórí ilé ẹni burúkú,+Àmọ́, ó ń bù kún ilé àwọn olódodo.+ Àìsáyà 3:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Sọ fún àwọn olódodo pé nǹkan máa lọ dáadáa fún wọn;Wọ́n máa jèrè iṣẹ́ ọwọ́ wọn.*+
32 Nítorí Jèhófà kórìíra oníbékebèke,+Ṣùgbọ́n àwọn adúróṣinṣin ni ọ̀rẹ́ Rẹ̀ tímọ́tímọ́.+ 33 Ègún Jèhófà wà lórí ilé ẹni burúkú,+Àmọ́, ó ń bù kún ilé àwọn olódodo.+