Àìsáyà 44:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí,Ọba Ísírẹ́lì+ àti Olùtúnrà rẹ̀,+ Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun: ‘Èmi ni ẹni àkọ́kọ́ àti ẹni ìkẹyìn.+ Kò sí Ọlọ́run kankan àfi èmi.+ Àìsáyà 63:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Torí ìwọ ni Bàbá wa;+Bí Ábúráhámù ò tiẹ̀ mọ̀ wá,Tí Ísírẹ́lì ò sì dá wa mọ̀,Ìwọ Jèhófà, ni Bàbá wa. Olùtúnrà wa látìgbà àtijọ́ ni orúkọ rẹ.+
6 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí,Ọba Ísírẹ́lì+ àti Olùtúnrà rẹ̀,+ Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun: ‘Èmi ni ẹni àkọ́kọ́ àti ẹni ìkẹyìn.+ Kò sí Ọlọ́run kankan àfi èmi.+
16 Torí ìwọ ni Bàbá wa;+Bí Ábúráhámù ò tiẹ̀ mọ̀ wá,Tí Ísírẹ́lì ò sì dá wa mọ̀,Ìwọ Jèhófà, ni Bàbá wa. Olùtúnrà wa látìgbà àtijọ́ ni orúkọ rẹ.+