ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 23:17, 18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Ní òpin àádọ́rin (70) ọdún, Jèhófà máa rántí Tírè, ó máa pa dà sídìí ọrọ̀ rẹ̀, á sì máa bá gbogbo ìjọba ayé tó wà lórí ilẹ̀ ayé ṣe ìṣekúṣe. 18 Àmọ́ èrè rẹ̀ àti ọrọ̀ rẹ̀ máa di ohun mímọ́ fún Jèhófà. Kò ní kó o pa mọ́ tàbí kó tò ó jọ, torí pé ọrọ̀ rẹ̀ máa di ti àwọn tó ń gbé iwájú Jèhófà, kí wọ́n lè jẹun ní àjẹyó, kí wọ́n sì wọ aṣọ aláràbarà.+

  • Àìsáyà 60:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  5 Ní àkókò yẹn, o máa rí i, o sì máa tàn yinrin,+

      Ọkàn rẹ máa lù kìkì, ó sì máa kún rẹ́rẹ́,

      Torí pé a máa darí ọrọ̀ òkun sọ́dọ̀ rẹ;

      Àwọn ohun àmúṣọrọ̀ àwọn orílẹ̀-èdè máa wá sọ́dọ̀ rẹ.+

  • Àìsáyà 60:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  7 A máa kó gbogbo agbo ẹran Kídárì+ jọ sọ́dọ̀ rẹ.

      Àwọn àgbò Nébáótì+ máa sìn ọ́.

      Wọ́n máa wá sórí pẹpẹ mi pẹ̀lú ìtẹ́wọ́gbà,+

      Màá sì ṣe ilé ológo mi* lọ́ṣọ̀ọ́.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́