ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 13:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Ọ̀rọ̀ ìkéde sí Bábílónì,+ tí Àìsáyà+ ọmọ Émọ́ọ̀sì rí nínú ìran:

  • Àìsáyà 13:21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 Àwọn ẹranko inú aṣálẹ̀ máa dùbúlẹ̀ síbẹ̀;

      Àwọn ẹyẹ òwìwí máa kún ilé wọn.

      Àwọn ògòǹgò á máa gbé ibẹ̀,+

      Àwọn ewúrẹ́ igbó* á máa tọ kiri níbẹ̀.

  • Jeremáyà 50:35
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 35 “Idà kan wà tó dojú kọ àwọn ará Kálídíà,” ni Jèhófà wí,

      “Ó dojú kọ àwọn tó ń gbé ní Bábílónì, ó sì dojú kọ àwọn ìjòyè rẹ̀ àti àwọn ọlọ́gbọ́n rẹ̀.+

  • Jeremáyà 50:39
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 39 Nítorí náà, àwọn ẹranko tó ń gbé ní aṣálẹ̀ á máa gbé pẹ̀lú àwọn ẹranko tó ń hu,

      Inú rẹ̀ sì ni ògòǹgò á máa gbé.+

      Ẹnikẹ́ni ò sì ní gbé ibẹ̀ mọ́ láé,

      Bẹ́ẹ̀ ni kò ní jẹ́ ibi tí àwọn èèyàn á máa gbé láti ìran dé ìran.”+

  • Ìfihàn 18:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Ó sì fi ohùn tó le ké jáde pé: “Ó ti ṣubú! Bábílónì Ńlá ti ṣubú,+ ó sì ti di ibi tí àwọn ẹ̀mí èṣù ń gbé àti ibi tí gbogbo ẹ̀mí àìmọ́* àti gbogbo ẹyẹ àìmọ́ tí a kórìíra ń lúgọ sí!+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́