ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Sámúẹ́lì 4:10, 11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Torí náà, àwọn Filísínì jà, wọ́n ṣẹ́gun Ísírẹ́lì,+ kálukú wọn sì sá lọ sí ilé rẹ̀. Ìpakúpa náà pọ̀; ọ̀kẹ́ kan ààbọ̀ (30,000) àwọn ọmọ ogun tó ń fẹsẹ̀ rìn ló kú lára àwọn ọmọ Ísírẹ́lì. 11 Yàtọ̀ síyẹn, wọ́n gba Àpótí Ọlọ́run, àwọn ọmọ Élì méjèèjì, Hófínì àti Fíníhásì sì kú.+

  • Sáàmù 78:60
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 60 Níkẹyìn, ó pa àgọ́ ìjọsìn Ṣílò tì,+

      Àgọ́ tí ó gbé inú rẹ̀ láàárín àwọn èèyàn.+

  • Jeremáyà 26:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Sọ fún wọn pé: “Ohun tí Jèhófà sọ nìyí, ‘Bí ẹ kò bá fetí sí mi láti máa tẹ̀ lé òfin* mi tí mo fún yín,

  • Jeremáyà 26:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 nígbà náà, ńṣe ni màá ṣe ilé yìí bíi Ṣílò,+ màá sì sọ ìlú yìí di ibi ègún lójú gbogbo orílẹ̀-èdè tó wà láyé.’”’”+

  • Ìdárò 2:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  7 Jèhófà ti pa pẹpẹ rẹ̀ tì;

      Ó ti ta ibi mímọ́ rẹ̀ nù.+

      Ó ti fi ògiri àwọn ilé gogoro rẹ̀ tó láàbò lé ọ̀tá lọ́wọ́.+

      Wọ́n ti gbé ohùn wọn sókè ní ilé Jèhófà,+ bíi ti ọjọ́ àjọyọ̀.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́