ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 2:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Àwọn ọlọ́run tí kò ní láárí máa pòórá pátápátá.+

  • Jeremáyà 51:17, 18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Kálukú ń hùwà láìronú, wọn ò sì ní ìmọ̀.

      Ojú á ti gbogbo oníṣẹ́ irin nítorí ère tí wọ́n ṣe;+

      Nítorí ère onírin* rẹ̀ jẹ́ èké,

      Kò sì sí ẹ̀mí* kankan nínú wọn.+

      18 Ẹ̀tàn* ni wọ́n,+ iṣẹ́ yẹ̀yẹ́ sì ni wọ́n.

      Nígbà tí ọjọ́ ìbẹ̀wò wọn bá dé, wọ́n á ṣègbé.

  • Sefanáyà 2:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Jèhófà máa dẹ́rù bà wọ́n;*

      Nítorí ó máa mú kí gbogbo àwọn ọlọ́run tó wà ní ayé di asán,*

      Gbogbo erékùṣù àwọn orílẹ̀-èdè á sì forí balẹ̀ fún un,*+

      Láti ibi tí kálukú wọn wà.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́