-
Jeremáyà 19:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Màá sọ ìlú yìí di ohun àríbẹ̀rù àti ohun àrísúfèé. Gbogbo ẹni tó bá ń gba ibẹ̀ kọjá á wò ó, ẹ̀rù á bà á, á sì súfèé nítorí ìyọnu rẹ̀.+
-
-
Míkà 6:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Torí ò ń tẹ̀ lé òfin Ómírì àti gbogbo ohun tí wọ́n ṣe ní ilé Áhábù,+
O sì ń tẹ̀ lé ìmọ̀ràn wọn.
-