Jeremáyà 44:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 44 Ọ̀rọ̀ tí Jeremáyà gbọ́ nípa gbogbo Júù tó ń gbé ní ilẹ̀ Íjíbítì,+ ìyẹn àwọn tó ń gbé ní Mígídólì,+ ní Tápánẹ́sì,+ ní Nófì*+ àti ní ilẹ̀ Pátírọ́sì,+ pé: Jeremáyà 46:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ọ̀rọ̀ tí Jèhófà sọ fún wòlíì Jeremáyà nípa bí Nebukadinésárì* ọba Bábílónì ṣe máa wá pa ilẹ̀ Íjíbítì rẹ́ nìyí:+
44 Ọ̀rọ̀ tí Jeremáyà gbọ́ nípa gbogbo Júù tó ń gbé ní ilẹ̀ Íjíbítì,+ ìyẹn àwọn tó ń gbé ní Mígídólì,+ ní Tápánẹ́sì,+ ní Nófì*+ àti ní ilẹ̀ Pátírọ́sì,+ pé:
13 Ọ̀rọ̀ tí Jèhófà sọ fún wòlíì Jeremáyà nípa bí Nebukadinésárì* ọba Bábílónì ṣe máa wá pa ilẹ̀ Íjíbítì rẹ́ nìyí:+