Jeremáyà 25:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 “‘Ṣùgbọ́n tí àádọ́rin (70) ọdún bá pé,+ màá pe ọba Bábílónì àti orílẹ̀-èdè yẹn wá jíhìn* nítorí ẹ̀ṣẹ̀ wọn,’+ ni Jèhófà wí, ‘màá sì sọ ilẹ̀ àwọn ará Kálídíà di ahoro títí láé.+ Jeremáyà 25:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Nítorí ọ̀pọ̀ orílẹ̀-èdè àti àwọn ọba ńlá+ á sọ wọ́n di ẹrú,+ màá sì san èrè wọn pa dà fún wọn gẹ́gẹ́ bí ìwà àti iṣẹ́ ọwọ́ wọn.’”+ Jeremáyà 51:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 “Ẹ dán ọfà;+ ẹ gbé àwọn apata ribiti.* Jèhófà ti ru ẹ̀mí àwọn ọba Mídíà sókè,+Torí ó ní in lọ́kàn láti pa Bábílónì run. Nítorí ẹ̀san Jèhófà nìyí, ẹ̀san nítorí tẹ́ńpìlì rẹ̀.
12 “‘Ṣùgbọ́n tí àádọ́rin (70) ọdún bá pé,+ màá pe ọba Bábílónì àti orílẹ̀-èdè yẹn wá jíhìn* nítorí ẹ̀ṣẹ̀ wọn,’+ ni Jèhófà wí, ‘màá sì sọ ilẹ̀ àwọn ará Kálídíà di ahoro títí láé.+
14 Nítorí ọ̀pọ̀ orílẹ̀-èdè àti àwọn ọba ńlá+ á sọ wọ́n di ẹrú,+ màá sì san èrè wọn pa dà fún wọn gẹ́gẹ́ bí ìwà àti iṣẹ́ ọwọ́ wọn.’”+
11 “Ẹ dán ọfà;+ ẹ gbé àwọn apata ribiti.* Jèhófà ti ru ẹ̀mí àwọn ọba Mídíà sókè,+Torí ó ní in lọ́kàn láti pa Bábílónì run. Nítorí ẹ̀san Jèhófà nìyí, ẹ̀san nítorí tẹ́ńpìlì rẹ̀.