ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 4:26
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 26 mo fi ọ̀run àti ayé ṣe ẹlẹ́rìí ta kò yín lónìí, pé ó dájú pé kíákíá lẹ máa pa run ní ilẹ̀ tí ẹ̀ ń sọdá Jọ́dánì láti lọ gbà. Ẹ ò ní pẹ́ níbẹ̀, ṣe lẹ máa pa run pátápátá.+

  • Ìdárò 2:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  2 Jèhófà ti gbé gbogbo ibùgbé Jékọ́bù mì, kò sì ṣàánú rẹ̀ rárá.

      Ó ti ya àwọn ibi olódi ọmọbìnrin Júdà lulẹ̀ nínú ìbínú rẹ̀.+

      Ó ti rẹ ìjọba + náà àti àwọn olórí+ rẹ̀ wálẹ̀, ó sì ti sọ wọ́n di aláìmọ́.

  • Ìsíkíẹ́lì 9:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Àmọ́ ní tèmi, mi ò ní ṣàánú wọn, mi ò sì ní yọ́nú sí wọn.+ Màá fi ìwà wọn san wọ́n lẹ́san.”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́