-
Ìsíkíẹ́lì 22:31Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
31 Torí náà, màá bínú sí wọn gidigidi, màá sì fi ìbínú mi tó ń jó bí iná pa wọ́n run. Màá fi ìwà wọn san wọ́n lẹ́san,’ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí.”
-