Diutarónómì 32:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Torí ìbínú mi ti mú kí iná+ sọ,Ó sì máa jó wọnú Isà Òkú,*+Ó máa jó ayé àti èso rẹ̀ run,Iná á sì ran ìpìlẹ̀ àwọn òkè. Àìsáyà 42:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Torí náà, Ó ń da ìhónú lé e lórí,Ìrunú rẹ̀ àti ìbínú ogun.+ Ó jẹ gbogbo ohun tó yí i ká run, àmọ́ kò fiyè sí i.+ Ó jó o, àmọ́ kò fọkàn sí i.+ Jeremáyà 7:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Torí náà, ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí, ‘Wò ó! Ìbínú mi àti ìrunú mi yóò dà sórí ibí yìí,+ sórí èèyàn àti ẹranko, sórí igi oko àti èso ilẹ̀. Ìbínú mi yóò máa jó bí iná tí kò ṣeé pa.’+
22 Torí ìbínú mi ti mú kí iná+ sọ,Ó sì máa jó wọnú Isà Òkú,*+Ó máa jó ayé àti èso rẹ̀ run,Iná á sì ran ìpìlẹ̀ àwọn òkè.
25 Torí náà, Ó ń da ìhónú lé e lórí,Ìrunú rẹ̀ àti ìbínú ogun.+ Ó jẹ gbogbo ohun tó yí i ká run, àmọ́ kò fiyè sí i.+ Ó jó o, àmọ́ kò fọkàn sí i.+
20 Torí náà, ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí, ‘Wò ó! Ìbínú mi àti ìrunú mi yóò dà sórí ibí yìí,+ sórí èèyàn àti ẹranko, sórí igi oko àti èso ilẹ̀. Ìbínú mi yóò máa jó bí iná tí kò ṣeé pa.’+