Àìsáyà 40:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ó máa bójú tó* agbo ẹran rẹ̀ bíi ti olùṣọ́ àgùntàn.+ Ó máa fi apá rẹ̀ kó àwọn ọ̀dọ́ àgùntàn jọ,Ó sì máa gbé wọn sí àyà rẹ̀. Ó máa rọra da àwọn tó ń fọ́mọ lọ́mú.+ Jeremáyà 23:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 “Ìgbà náà ni màá kó àwọn tó ṣẹ́ kù lára àgùntàn mi jọ láti gbogbo ilẹ̀ tí mo fọ́n wọn ká sí,+ màá sì mú wọn pa dà wá sí ibi ìjẹko wọn,+ wọ́n á máa bímọ, wọ́n á sì di púpọ̀.+
11 Ó máa bójú tó* agbo ẹran rẹ̀ bíi ti olùṣọ́ àgùntàn.+ Ó máa fi apá rẹ̀ kó àwọn ọ̀dọ́ àgùntàn jọ,Ó sì máa gbé wọn sí àyà rẹ̀. Ó máa rọra da àwọn tó ń fọ́mọ lọ́mú.+
3 “Ìgbà náà ni màá kó àwọn tó ṣẹ́ kù lára àgùntàn mi jọ láti gbogbo ilẹ̀ tí mo fọ́n wọn ká sí,+ màá sì mú wọn pa dà wá sí ibi ìjẹko wọn,+ wọ́n á máa bímọ, wọ́n á sì di púpọ̀.+