Àìsáyà 13:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ọ̀rọ̀ ìkéde sí Bábílónì,+ tí Àìsáyà+ ọmọ Émọ́ọ̀sì rí nínú ìran: Àìsáyà 13:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Torí àwọn ìràwọ̀ ojú ọ̀run àti àwọn àgbájọ ìràwọ̀ wọn*+Kò ní tan ìmọ́lẹ̀ wọn jáde;Oòrùn máa ṣókùnkùn tó bá ràn,Òṣùpá ò sì ní tan ìmọ́lẹ̀ rẹ̀.
10 Torí àwọn ìràwọ̀ ojú ọ̀run àti àwọn àgbájọ ìràwọ̀ wọn*+Kò ní tan ìmọ́lẹ̀ wọn jáde;Oòrùn máa ṣókùnkùn tó bá ràn,Òṣùpá ò sì ní tan ìmọ́lẹ̀ rẹ̀.