ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Kíróníkà 36:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Yàtọ̀ síyẹn, ọba Íjíbítì fi Élíákímù arákùnrin Jèhóáhásì jọba lórí Júdà àti Jerúsálẹ́mù, ó sì yí orúkọ rẹ̀ pa dà sí Jèhóákímù; ṣùgbọ́n Nékò+ mú Jèhóáhásì arákùnrin rẹ̀, ó sì mú un wá sí Íjíbítì.+

  • Jeremáyà 22:18, 19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 “Nítorí náà, ohun tí Jèhófà sọ nípa Jèhóákímù+ ọmọ Jòsáyà, ọba Júdà nìyí,

      ‘Wọn kò ní ṣọ̀fọ̀ rẹ̀ pé:

      “Áà, arákùnrin mi! Áà, arábìnrin mi!”

      Wọn kò sì ní ṣọ̀fọ̀ rẹ̀ pé:

      “Áà, ọ̀gá! Áà, kábíyèsí!”

      19 Bí wọ́n ṣe ń sin kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ ni wọ́n máa sin ín,+

      Wọ́n á wọ́ ọ kiri, wọ́n á sì gbé e sọ nù,

      Sí ìta ẹnubodè Jerúsálẹ́mù.’+

  • Jeremáyà 36:30
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 30 Nítorí náà, ohun tí Jèhófà sọ nìyí sí Jèhóákímù ọba Júdà, ‘Kò ní lẹ́nì kankan tó máa jókòó sórí ìtẹ́ Dáfídì,+ òkú rẹ̀ á sì wà ní ìta nínú ooru lọ́sàn-án àti nínú òtútù lóru.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́