Sáàmù 90:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Kí a tó bí àwọn òkèTàbí kí o tó dá ayé àti ilẹ̀ tó ń méso jáde,*+Láti ayérayé dé ayérayé,* ìwọ ni Ọlọ́run.+ Dáníẹ́lì 7:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 “Mò ń wò nínú ìran òru, sì wò ó! ẹnì kan bí ọmọ èèyàn+ ń bọ̀ pẹ̀lú ìkùukùu* ojú ọ̀run; a jẹ́ kó wọlé wá sọ́dọ̀ Ẹni Ọjọ́ Àtayébáyé,+ wọ́n sì mú un wá sún mọ́ iwájú Ẹni yẹn. Dáníẹ́lì 7:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 títí Ẹni Ọjọ́ Àtayébáyé+ fi dé, tí a sì dá àwọn ẹni mímọ́ ti Onípò Àjùlọ láre,+ àkókò tí a yàn pé kí àwọn ẹni mímọ́ gba ìjọba sì dé.+ Hábákúkù 1:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Jèhófà, ṣebí láti ayérayé ni ìwọ ti wà?+ Ọlọ́run mi, Ẹni Mímọ́ mi, ìwọ kì í kú.*+ Jèhófà, ìwọ lo yàn wọ́n láti ṣèdájọ́;Àpáta mi,+ o lò wọ́n láti fìyà jẹni.*+
2 Kí a tó bí àwọn òkèTàbí kí o tó dá ayé àti ilẹ̀ tó ń méso jáde,*+Láti ayérayé dé ayérayé,* ìwọ ni Ọlọ́run.+
13 “Mò ń wò nínú ìran òru, sì wò ó! ẹnì kan bí ọmọ èèyàn+ ń bọ̀ pẹ̀lú ìkùukùu* ojú ọ̀run; a jẹ́ kó wọlé wá sọ́dọ̀ Ẹni Ọjọ́ Àtayébáyé,+ wọ́n sì mú un wá sún mọ́ iwájú Ẹni yẹn.
22 títí Ẹni Ọjọ́ Àtayébáyé+ fi dé, tí a sì dá àwọn ẹni mímọ́ ti Onípò Àjùlọ láre,+ àkókò tí a yàn pé kí àwọn ẹni mímọ́ gba ìjọba sì dé.+
12 Jèhófà, ṣebí láti ayérayé ni ìwọ ti wà?+ Ọlọ́run mi, Ẹni Mímọ́ mi, ìwọ kì í kú.*+ Jèhófà, ìwọ lo yàn wọ́n láti ṣèdájọ́;Àpáta mi,+ o lò wọ́n láti fìyà jẹni.*+