Jeremáyà 31:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Wọ́n á wá pẹ̀lú ẹkún.+ Màá máa darí wọn bí wọ́n ṣe ń wá ojú rere. Màá ṣamọ̀nà wọn lọ sí ìṣàn* omi,+Lórí ọ̀nà tó tẹ́jú tí wọn ò ti ní kọsẹ̀. Nítorí èmi ni Bàbá Ísírẹ́lì, Éfúrémù sì ni àkọ́bí mi.”+ Jeremáyà 31:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 “Ǹjẹ́ Éfúrémù kì í ṣe ọmọ mi àtàtà, ọmọ tí mo nífẹ̀ẹ́?+ Torí bí mo ṣe ń sọ̀rọ̀ sí i tó, síbẹ̀ mo ṣì ń rántí rẹ̀. Ìdí nìyẹn tí ọkàn* mi fi gbé sókè nítorí rẹ̀.+ Ó sì dájú pé màá ṣàánú rẹ̀,” ni Jèhófà wí.+
9 Wọ́n á wá pẹ̀lú ẹkún.+ Màá máa darí wọn bí wọ́n ṣe ń wá ojú rere. Màá ṣamọ̀nà wọn lọ sí ìṣàn* omi,+Lórí ọ̀nà tó tẹ́jú tí wọn ò ti ní kọsẹ̀. Nítorí èmi ni Bàbá Ísírẹ́lì, Éfúrémù sì ni àkọ́bí mi.”+
20 “Ǹjẹ́ Éfúrémù kì í ṣe ọmọ mi àtàtà, ọmọ tí mo nífẹ̀ẹ́?+ Torí bí mo ṣe ń sọ̀rọ̀ sí i tó, síbẹ̀ mo ṣì ń rántí rẹ̀. Ìdí nìyẹn tí ọkàn* mi fi gbé sókè nítorí rẹ̀.+ Ó sì dájú pé màá ṣàánú rẹ̀,” ni Jèhófà wí.+