A7-F
Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Pàtàkì Nínú Ìgbésí Ayé Jésù—Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Tí Jésù Tún Ṣe ní Ìlà Oòrùn Jọ́dánì
| ÀKÓKÒ | IBI | ÌṢẸ̀LẸ̀ | MÁTÍÙ | MÁÀKÙ | LÚÙKÙ | JÒHÁNÙ | 
|---|---|---|---|---|---|---|
| 32, lẹ́yìn Àjọyọ̀ Ìyàsímímọ́ | Bẹ́tánì ní òdìkejì | Jọ́dánì Ó lọ síbi tí Jòhánù ti ń ṣèrìbọmi fún àwọn èèyàn; ọ̀pọ̀ gba Jésù gbọ́ | ||||
| Pèríà | Ó rọ àwọn èèyàn pé kí wọ́n gba ẹnu ọ̀nà tóóró wọlé; ó kédàárò lórí Jerúsálẹ́mù | |||||
| Ó rọ àwọn èèyàn pé kí wọ́n gba ẹnu ọ̀nà tóóró wọlé; ó kédàárò lórí Jerúsálẹ́mù | ||||||
| Ó ṣeé ṣe kó jẹ́ ní Pèríà | Ó kọ́ni ní ìwà ìrẹ̀lẹ̀; àwọn àpèjúwe: ibi tó lọ́lá jù àtàwọn tí wọ́n pè tó ń ṣàwáwí | |||||
| Ronú lórí ohun tó máa náni láti di ọmọ ẹ̀yìn | ||||||
| Àwọn àpèjúwe: àgùntàn tó sọ nù, ẹyọ owó tó sọ nù, ọmọkùnrin tó sọ nù | ||||||
| Àwọn àpèjúwe: ìríjú aláìṣòdodo, ọkùnrin ọlọ́rọ̀ àti Lásárù | ||||||
| Ẹ̀kọ́ nípa ìkọsẹ̀, ìdáríjì àti ìgbàgbọ́ | ||||||
| Bẹ́tánì | Lásárù kú, ó sì jíǹde | |||||
| Jerúsálẹ́mù; Éfúrémù | Wọ́n gbìmọ̀ pọ̀ láti pa Jésù; ó kúrò níbẹ̀ | |||||
| Samáríà; Gálílì | Ó wo adẹ́tẹ̀ mẹ́wàá sàn; ó sọ bí Ìjọba Ọlọ́run ṣe máa dé | |||||
| Samáríà tàbí Gálílì | Àwọn àpèjúwe: opó tí kò yéé bẹ̀bẹ̀, Farisí àti agbowó orí | |||||
| Pèríà | Ó kọ́ni nípa ìgbéyàwó àti ìkọ̀sílẹ̀ | |||||
| Ó súre fún àwọn ọmọdé | ||||||
| Ìbéèrè ọkùnrin ọlọ́rọ̀ náà; àpèjúwe nípa àwọn òṣìṣẹ́ ọgbà àjàrà àti owó iṣẹ́ wọn tó dọ́gba | ||||||
| Ó ṣeé ṣe kó jẹ́ ní Pèríà | Ó sọ àsọtẹ́lẹ̀ nípa ikú rẹ̀ nígbà kẹta | |||||
| Jémíìsì àti Jòhánù fẹ́ gba ipò nínú Ìjọba Ọlọ́run | ||||||
| Jẹ́ríkò | Jẹ́ríkò Ó gba ibẹ̀ kọjá, ó la ojú ọkùnrin méjì tó jẹ́ afọ́jú; ó lọ sọ́dọ̀ Sákéù; àpèjúwe mínà mẹ́wàá |