Àpéjọ Àyíká Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ 2017
Ẹṣin Ọ̀rọ̀: Jẹ́ Kí Ìgbàgbọ́ Rẹ Nínú Jèhófà Máa Lágbára Sí I!—Héb. 11:6
Òwúrọ̀
- 9:30 [11:30]a Ohùn Orin 
- 9:40 [11:40] Orin 12 àti Àdúrà 
- 9:50 [11:50] Lábẹ́ Ipòkípò, “Ẹ Ní Ìgbàgbọ́ Nínú Ọlọ́run” 
- 10:05 [12:05] Àpínsọ Àsọyé: Àwọn Àfiwé Ọ̀rọ̀ Tó Ń Mú Kí Ìgbàgbọ́ Ẹni Nínú Jèhófà Lágbára - Apata 
- Baba 
- Àpáta 
- Olùṣọ́ Àgùntàn 
 
- 11:05 [1:05] Orin 22 àti Ìfilọ̀ 
- 11:15 [1:15] “Ràn Mí Lọ́wọ́ Níbi Tí Mo Ti Nílò Ìgbàgbọ́!” 
- 11:30 [1:30] Ìyàsímímọ́ àti Ìrìbọmi 
- 12:00 [2:00] Orin 7 
Ọ̀sán
- 1:10 [2:40] Ohùn Orin 
- 1:20 [2:50] Orin 54 àti Àdúrà 
- 1:30 [3:00] Àsọyé fún Gbogbo Ènìyàn: Kí Ni Ìgbàgbọ́, Báwo La Ṣe Lè Fi Hàn Pé A Nígbàgbọ́? 
- 2:00 [3:30] Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́ 
- 2:30 [4:00] Orin 30 àti Ìfilọ̀ 
- 2:40 [4:10] Àpínsọ Àsọyé: ‘Mú Ẹ̀ṣẹ̀ Tó Máa Ń Wé Mọ́ Wa Pẹ̀lú Ìrọ̀rùn Kúrò’ - Jèhófà Máa Mú Ìwà Búburú Kúrò 
- Jèhófà Máa Pèsè Àwọn Ohun Kòṣeémáàní fún Wa 
- Jèhófà Máa Jí Àwọn Òkú Dìde 
 
- 3:40 [5:10] Ìgbàgbọ́ Tó Jinlẹ̀ Ń Mú Èrè Wá 
- 4:15 [5:45] Orin 43 àti Àdúrà 
a Àkókò tó wà nínú àkámọ́ [ ] ni a ó tẹ̀ lé tó bá jẹ́ ọjọ́ Sátidé “Gbálùúmọ́”