“Ẹ Ní Ìgbàgbọ́”!
ÒWÚRỌ̀
- 9:30 Ohùn Orin 
- 9:40 Orin 118 àti Àdúrà 
- 9:50 Báwo La Ṣe Lè “Ní Ìgbàgbọ́,” Kí sì Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Ní In? 
- 10:05 Àpínsọ Àsọyé: Máa Fara Wé Àwọn Tó Nígbàgbọ́ - • Ísákì àti Rèbékà 
- • Ẹ́sítà 
- • Tímótì 
 
- 11:05 Orin 60 àti Ìfilọ̀ 
- 11:15 ‘A Ní Ìgbàgbọ́, Torí Náà A Sọ̀rọ̀’ 
- 11:30 Ìyàsímímọ́ àti Ìrìbọmi 
- 12:00 Orin 52 
Ọ̀SÁN
- 1:10 Ohùn Orin 
- 1:20 Orin 9 àti Àdúrà 
- 1:30 Àsọyé fún Gbogbo Èèyàn: Ní Ìgbàgbọ́ Nínú Ọlọ́run “Tí Kò Lè Parọ́” 
- 2:00 Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́ 
- 2:30 Orin 54 àti Ìfilọ̀ 
- 2:40 Àpínsọ Àsọyé: Máa “Rìn Nípa Ìgbàgbọ́” Lójoojúmọ́ - • “Má Ṣàníyàn Láé” 
- • ‘Máa Lo Àkókò Rẹ Lọ́nà Tó Dára Jù Lọ’ 
- • Má Ṣe Jẹ́ “Apá Kan Ayé” 
 
- 3:40 “Jèhófà Mọ Àwọn Tó Jẹ́ Tirẹ̀” 
- 4:15 Orin 7 àti Àdúrà