Sunday
“Ẹni tí ó bá fara dà á dé òpin ni ẹni tí a ó gbà là”—MÁTÍÙ 24:13
ÒWÚRỌ̀
- 8:20 Fídíò Orin 
- 8:30 Orin 121 àti Àdúrà 
- 8:40 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: A Gbọ́dọ̀ ‘Fi Ìfaradà Sáré’ - Sáré Kó O Lè Gba Èrè! (1 Kọ́ríńtì 9:24) 
- Máa Kọ́ Ara Rẹ (1 Kọ́ríńtì 9:25-27) 
- Fi Àwọn Ẹrù Tí Kò Pọndandan Sílẹ̀ (Hébérù 12:1) 
- Máa Tẹ̀ Lé Àwọn Àpẹẹrẹ Rere (Hébérù 12:2, 3) 
- Máa Jẹ Oúnjẹ Tó Ń Ṣara Lóore (Hébérù 5:12-14) 
- Máa Mu Omi Dáadáa (Ìṣípayá 22:17) 
- Máa Tẹ̀ Lé Òfin Eré Sísá (2 Tímótì 2:5) 
- Jẹ́ Kó Dá Ọ Lójú Pé Wàá Gba Èrè (Róòmù 15:13) 
 
- 10:10 Orin 141 àti Ìfilọ̀ 
- 10:20 ÀSỌYÉ FÚN GBOGBO ÈNÌYÀN: Má Ṣe Sọ̀rètí Nù! (Aísáyà 48:17; Jeremáyà 29:11) 
- 10:50 Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́ 
- 11:20 Orin 20 àti Àkókò Ìsinmi 
Ọ̀SÁN
- 12:35 Fídíò Orin 
- 12:45 Orin 57 
- 12:50 ÀWÒKẸ́KỌ̀Ọ́: Ẹ Rántí Aya Lọ́ọ̀tì—Apá Kẹta (Lúùkù 17:28-33) 
- 1:20 Orin 54 àti Ìfilọ̀ 
- 1:30 ‘Máa Fojú Sọ́nà . . . Kò Ní Pẹ́ Mọ́!’ (Hábákúkù 2:3) 
- 2:30 Orin 129 àti Àdúrà Ìparí