Friday
“Ẹ máa yọ̀ nígbà gbogbo nínú Olúwa. Lẹ́ẹ̀kan sí i, mo sọ pé, Ẹ máa yọ̀!”—Fílípì 4:4
ÀÁRỌ̀
- 9:20 Fídíò Orin 
- 9:30 Orin 111 àti Àdúrà 
- 9:40 Ọ̀RỌ̀ ALÁGA: Ìdí Tí Jèhófà Fi Jẹ́ “Ọlọ́run Aláyọ̀” (1 Tímótì 1:11) 
- 10:15 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Kí Lá Jẹ́ Kó O Láyọ̀? - • Jẹ́ Kí Ohun Díẹ̀ Tẹ́ Ẹ Lọ́rùn (Oníwàásù 5:12) 
- • Ẹ̀rí Ọkàn Tó Mọ́ (Sáàmù 19:8) 
- • Iṣẹ́ Tó Ń Fini Lọ́kàn Balẹ̀ (Oníwàásù 4:6; 1 Kọ́ríńtì 15:58) 
- • Àwọn Ọ̀rẹ́ Tòótọ́ (Òwe 18:24; 19:4, 6, 7) 
 
- 11:05 Orin 89 àti Ìfilọ̀ 
- 11:15 BÍBÉLÌ KÍKÀ BÍ ẸNI ṢE ERÉ ÌTÀN: ‘Jèhófà Mú Kí Wọ́n Máa Yọ̀’ (Ẹ́sírà 1:1–6:22; Hágáì 1:2-11; 2:3-9; Sekaráyà 1:12-16; 2:7-9; 3:1, 2; 4:6, 7) 
- 11:45 Máa Yọ̀ Nítorí Àwọn Iṣẹ́ Ìgbàlà Jèhófà (Sáàmù 9:14; 34:19; 67:1, 2; Àìsáyà 12:2) 
- 12:15 Orin 148 àti Àkókò Ìsinmi 
Ọ̀SÁN
- 1:30 Fídíò Orin 
- 1:40 Orin 131 
- 1:45 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Jẹ́ Kí Ayọ̀ Wà Nínú Ìdílé Rẹ - • Ẹ̀yin Ọkọ, Ẹ Máa Yọ̀ Pẹ̀lú Ìyàwó Yín (Òwe 5:18, 19; 1 Pétérù 3:7) 
- • Ẹ̀yin Aya, Ẹ Máa Yọ̀ Pẹ̀lú Ọkọ Yín (Òwe 14:1) 
- • Ẹ̀yin Òbí, Ẹ Máa Yọ̀ Pẹ̀lú Àwọn Ọmọ Yín (Òwe 23:24, 25) 
- • Ẹ̀yin Ọ̀dọ́, Ẹ Máa Yọ̀ Pẹ̀lú Àwọn Òbí Yín (Òwe 23:22) 
 
- 2:50 Orin 135 àti Ìfilọ̀ 
- 3:00 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Àwọn Ohun Tí Jèhófà Dá Fi Hàn Pé Ó Fẹ́ Ká Máa Yọ̀ - • Àwọn Òdòdó Tó Rẹwà (Sáàmù 111:2; Mátíù 6:28-30) 
- • Oúnjẹ Aládùn (Oníwàásù 3:12, 13; Mátíù 4:4) 
- • Àwọ̀ Mèremère (Sáàmù 94:9) 
- • Ara Èèyàn (Ìṣe 17:28; Éfésù 4:16) 
- • Ohùn Tó Ń Tuni Lára (Òwe 20:12; Àìsáyà 30:21) 
- • Àwọn Ẹranko Àgbàyanu (Jẹ́nẹ́sísì 1:26) 
 
- 4:00 Kí Nìdí Tí ‘Àwọn Tó Ń Wá Àlàáfíà Fi Máa Ń Láyọ̀’? (Òwe 12:20; Jémíìsì 3:13-18; 1 Pétérù 3:10, 11) 
- 4:20 Àjọṣe Tímọ́tímọ́ Pẹ̀lú Jèhófà Lohun Tó Ń Fúnni Láyọ̀ Tó Ga Jù Lọ! (Sáàmù 25:14; Hábákúkù 3:17, 18) 
- 4:55 Orin 28 àti Àdúrà Ìparí