Saturday
“Ẹ máa fi orúkọ mímọ́ rẹ̀ yangàn. Kí ọkàn àwọn tó ń wá Jèhófà máa yọ̀”—Sáàmù 105:3
ÀÁRỌ̀
- 9:20 Fídíò Orin 
- 9:30 Orin 53 àti Àdúrà 
- 9:40 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Jẹ́ Kí Iṣẹ́ Sísọni Di Ọmọ Ẹ̀yìn Máa Fún Ẹ Láyọ̀—Túbọ̀ Já Fáfá - • Máa Lo Ìbéèrè (Jémíìsì 1:19) 
- • Jẹ́ Kí Àwọn Èèyàn Rí Agbára Tí Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Ní (Hébérù 4:12) 
- • Máa Fi Àpèjúwe Ṣàlàyé Kókó Pàtàkì (Mátíù 13:34, 35) 
- • Máa Lo Ìtara Tó O Bá Ń Kọ́ni (Róòmù 12:11) 
- • Máa Fọ̀rọ̀ Ro Ara Ẹ Wò (1 Tẹsalóníkà 2:7, 8) 
- • Jẹ́ Kí Ọ̀rọ̀ Rẹ Wọni Lọ́kàn (Òwe 3:1) 
 
- 10:50 Orin 58 àti Ìfilọ̀ 
- 11:00 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Jẹ́ Kí Iṣẹ́ Sísọni Di Ọmọ Ẹ̀yìn Máa Fún Ẹ Láyọ̀—Máa Lo Àwọn Nǹkan Tí Jèhófà Pèsè - • Àwọn Ohun Èlò Ìwádìí (1 Kọ́ríńtì 3:9; 2 Tímótì 3:16, 17) 
- • Àwọn Ará (Róòmù 16:3, 4; 1 Pétérù 5:9) 
- • Àdúrà (Sáàmù 127:1) 
 
- 11:45 ÌRÌBỌMI: Bí Ìrìbọmi Ṣe Máa Jẹ́ Kó O Túbọ̀ Láyọ̀ (Òwe 11:24; Ìfihàn 4:11) 
- 12:15 Orin 79 àti Àkókò Ìsinmi 
Ọ̀SÁN
- 1:35 Fídíò Orin 
- 1:45 Orin 76 
- 1:50 Bí Iṣẹ́ Sísọni Di Ọmọ Ẹ̀yìn Ṣe Ń Fún Àwọn Ará Wa Láyọ̀ ní . . . - • Áfíríkà 
- • Éṣíà 
- • Yúróòpù 
- • Amẹ́ríkà ti Àríwá 
- • Oceania 
- • Amẹ́ríkà ti Gúúsù 
 
- 2:35 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Ran Àwọn Tó Ò Ń Kọ́ Lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Lọ́wọ́ Láti . . . - • Máa Dá Kẹ́kọ̀ọ́ (Mátíù 5:3; Jòhánù 13:17) 
- • Máa Wá Sípàdé (Sáàmù 65:4) 
- • Yẹra fún Ẹgbẹ́ Búburú (Òwe 13:20) 
- • Jáwọ́ Nínú Ìwà Àìmọ́ (Éfésù 4:22-24) 
- • Ní Àjọṣe Tímọ́tímọ́ Pẹ̀lú Jèhófà (1 Jòhánù 4:8, 19) 
 
- 3:30 Orin 110 àti Ìfilọ̀ 
- 3:40 FÍÌMÙ: Nehemáyà: “Ìdùnnú Jèhófà Ni Ibi Ààbò Yín”—Apá Kìíní (Nehemáyà 1:1–6:19) 
- 4:15 Iṣẹ́ Sísọni Di Ọmọ Ẹ̀yìn ti Ìsinsìnyí Ń Múra Wa Sílẹ̀ De ti Ayé Tuntun (Àìsáyà 11:9; Ìṣe 24:15) 
- 4:50 Orin 140 àti Àdúrà Ìparí