Sunday
“Jẹ́ kí inú rẹ máa dùn jọjọ nínú Jèhófà, yóò sì fún ọ ní àwọn ohun tí ọkàn rẹ fẹ́”—Sáàmù 37:4
ÀÁRỌ̀
- 9:20 Fídíò Orin 
- 9:30 Orin 22 àti Àdúrà 
- 9:40 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: A Lè Láyọ̀ Bá A Tiẹ̀ Ń Dojú Kọ . . . - • Ìpọ́njú (Róòmù 5:3-5; 8:35, 37) 
- • Wàhálà (2 Kọ́ríńtì 4:8; 7:5) 
- • Inúnibíni (Mátíù 5:11, 12) 
- • Ebi (Fílípì 4:11-13) 
- • Ìhòòhò (1 Kọ́ríńtì 4:11, 16) 
- • Ewu (2 Kọ́ríńtì 1:8-11) 
- • Idà (2 Tímótì 4:6-8) 
 
- 11:10 Orin 9 àti Ìfilọ̀ 
- 11:20 ÀSỌYÉ FÚN GBOGBO ÈÈYÀN: Báwo Lo Ṣe Lè Ní Ọrọ̀ Láìsí Ìrora? (Òwe 10:22; 1 Tímótì 6:9, 10; Ìfihàn 21:3-5) 
- 11:50 Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́ 
- 12:20 Orin 84 àti Àkókò Ìsinmi 
Ọ̀SÁN
- 1:40 Fídíò Orin 
- 1:50 Orin 62 
- 1:55 FÍÌMÙ: Nehemáyà: “Ìdùnnú Jèhófà Ni Ibi Ààbò Yín”—Apá Kejì (Nehemáyà 8:1–13:30; Málákì 1:6–3:18) 
- 2:40 Orin 71 àti Ìfilọ̀ 
- 2:50 “Jẹ́ Kí Inú Rẹ Máa Dùn Jọjọ Nínú Jèhófà”!(Sáàmù 16:8, 9, 11; 37:4) 
- 3:50 Orin Tuntun àti Àdúrà Ìparí