Sunday
“Jèhófà ń fi sùúrù dúró láti ṣojúure sí yín”—Àìsáyà 30:18
Àárọ̀
- 9:20 Fídíò Orin 
- 9:30 Orin 95 àti Àdúrà 
- 9:40 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Máa Ní Sùúrù Bíi Tàwọn Wòlíì - • Èlíjà (Jémíìsì 5:10, 17, 18) 
- • Míkà (Míkà 7:7) 
- • Hósíà (Hósíà 3:1) 
- • Àìsáyà (Àìsáyà 7:3) 
- • Ìsíkíẹ́lì (Ìsíkíẹ́lì 2:3-5) 
- • Jeremáyà (Jeremáyà 15:16) 
- • Dáníẹ́lì (Dáníẹ́lì 9:22, 23) 
 
- 11:05 Orin 142 àti Ìfilọ̀ 
- 11:15 ÀSỌYÉ FÚN GBOGBO ÈÈYÀN: Ọlọ́run Máa Dáhùn Àdúrà Ẹ (Àìsáyà 64:4) 
- 11:45 Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́ 
- 12:15 Orin 94 àti Àkókò Ìsinmi 
Ọ̀sán
- 1:35 Fídíò Orin 
- 1:45 Orin 114 
- 1:50 FÍDÍÒ: “Fi Ọ̀nà Rẹ Lé Jèhófà Lọ́wọ́”—Apá 2 (Sáàmù 37:5) 
- 2:30 Orin 115 àti Ìfilọ̀ 
- 2:40 “Jèhófà Ń Fi Sùúrù Dúró Láti Ṣojúure sí Yín” (Àìsáyà 30:18-21; 60:17; 2 Àwọn Ọba 6:15-17; Éfésù 1:9, 10) 
- 3:40 Orin Tuntun àti Àdúrà Ìparí