Atọ́ka Kókó Àpilẹ̀kọ Fún Ilé Ìṣọ́ 1999
Ó ń tọ́ka sí ìtẹ̀jáde tí àpilẹ̀kọ kọ̀ọ̀kan ti jáde
ÀWỌN ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ
“Àbẹ̀wò Mi sí Gbọ̀ngàn Ìjọba,” 11/15
Àlàáfíà ní Orílẹ̀-Èdè Tó Kún fún Wàhálà (Northern Ireland), 12/15
Àpéjọpọ̀ Àgbègbè “Ọ̀nà Ìgbésí Ayé Tí Ọlọ́run Fẹ́,” 1/15
Àpéjọpọ̀ Àgbègbè “Ọ̀rọ̀ Àsọtẹ́lẹ̀ Ọlọ́run,” 2/15
Àwọn Aláṣẹ Gbóríyìn, 4/1
Ayẹyẹ Ìkẹ́kọ̀ọ́yege ní Gilead, 6/1, 12/15
“Ẹ Ti Yí Èrò Mi Padà,” 9/15
Ìbẹ̀wò Pàtàkì Mú Erékùṣù Kan Yọ̀ Ṣẹ̀ṣẹ̀ (Cuba), 5/15
Ìfẹ́ Tí A Ní sí “Àwọn Tí Ó Bá Wa Tan Nínú Ìgbàgbọ́” (ìjábá Chile), 6/15
Ilẹ̀ Àwọn Venda Abèso Wọ̀ǹtìwọnti, 5/1
‘Iná Ẹ̀mí Ìtọpinpin’ (ìwé Creator), 6/15
Ìyàsímímọ́ Ibùdó Ìdánilẹ́kọ̀ọ́ ti Watchtower, 11/15
Namibia, 7/15
Nígbà Tí Ìwà Ọ̀làwọ́ Bá Pọ̀ Gidigidi (ọrẹ), 11/1
Ǹjẹ́ O Lè Sìn ní Ilẹ̀ Òkèèrè? 10/15
‘Ọkọ Tó Láyọ̀ Nítorí Tí Ó Ní Aya Rere,’ 9/1
St. Helena, 2/1
ÀWỌN OLÙPÒKÌKÍ ÌJỌBA RÒYÌN
2/1, 4/1, 6/1, 8/1, 12/1
BÍBÉLÌ
Gbára Lé Àsọtẹ́lẹ̀ Bíbélì, 7/15
Ìṣẹ̀lẹ̀ Mánigbàgbé Fáwọn Tó Fẹ́ràn Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run (Ìtumọ̀ Ayé Tuntun), 10/15
Jerome—Òléwájú Nínú Ìtumọ̀ Bíbélì, 1/1
Ǹjẹ́ Ó Lè Ràn Wá Lọ́wọ́ Lóde Òní? 11/15
Ọ̀rọ̀ Ọgbọ́n fún Òde Ìwòyí, 4/1
Ṣíṣàlàyé Bíbélì—Ta Ló Ń Darí Rẹ̀? 8/1
ÌBÉÈRÈ LÁTI ỌWỌ́ ÀWỌN ÒǸKÀWÉ
Ìfẹ́sọ́nà, 8/15
Iṣẹ́ abẹ sísọni di aláìlèbímọ fún ìfètòsọ́mọbíbí, 6/15
Iṣẹ́ tó ní í ṣe pẹ̀lú ilé ìjọsìn, 4/15
‘Sísàmì’ (2 Tẹ 3:14), 7/15
ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI ÀNÍMỌ́ KRISTẸNI
A Fún Wọn Lókun Láti Sọ Pé A Ò Jẹ́ Hùwà Àìtọ́, 10/1
Àwọn Èèyàn Ha Ń Gba Ìmọ̀ràn Rẹ Bí? 1/15
Àwọn Ìdílé Ńlá Tó Ṣọ̀kan Nínú Iṣẹ́ Ìsìn Ọlọ́run, 2/15
Báa Ṣe Lè Mọ Àìlera Tẹ̀mí Kí A sì Borí Rẹ̀, 4/15
Èé Ṣe Tó Fi Yẹ Kóo Máa Mú Ìlérí Rẹ Ṣẹ? 9/15
Ẹ̀mí Ìrẹ̀lẹ̀, 2/1
Ẹ̀mí Ṣohun-Tẹ́gbẹ́-Ń-Ṣe, 8/1
“Fi Ìbùkún fún Jèhófà, Ìwọ Ọkàn Mi,” 5/15
Ìdílé Onígbeyàwó Àtúnṣe Lè Ṣàṣeyọrí, 3/1
Ìgbéyàwó Aláṣeyọrí, 2/15
Ìjọ Kristẹni—Àrànṣe Afúnnilókun, 5/15
Ìjùmọ̀sọ̀rọ̀—Àṣírí Ìgbéyàwó Aláṣeyọrí, 7/15
Ìrẹ̀wẹ̀sì, 11/15
Jẹ́ Kí Òye Rẹ Kún? 6/15
Jíjàǹfààní Látinú “Ọkà Ọ̀run,” 8/15
Kíkọ́ Ìfẹ́ Títayọ, 10/15
Máa Fi Hàn Pé O Moore, 4/15
Máà Jẹ́ Kí Àníyàn Borí Rẹ, 3/15
Máà Jẹ́ Kí Ìbínú Mú Ọ Kọsẹ̀, 8/15
Máa Kàwé Pẹ̀lú Àwọn Ọmọ Rẹ, 5/1
Má Ṣe Jẹ́ Kí Ànímọ́ Rere Rẹ Di Àbùkù Rẹ, 12/1
Ní Ọgbọ́n, Kí O Sì Gba Ìbáwí, 9/15
Rírú Ẹbọ Tí Jèhófà Yóò Tẹ́wọ́ Gbà, 2/1
Ṣé Ojú Tí Ọlọ́run Fi Ń Wo Àwọn Oníwà Ipá? 12/15
Ta Ló Ń Darí Èrò Rẹ? 4/1
ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ
“Aṣiṣẹ́ Tí Kò Ní Ohun Kankan Láti Tì í Lójú” (A. Soppa), 1/1
Àwọn Òbí Wa Kọ́ Wa Láti Nífẹ̀ẹ́ Ọlọ́run (E. Tracy), 12/1
Fífi Tayọ̀tayọ̀ Tẹ́wọ́ Gba Ìdarí Jèhófà (U. Glass), 8/1
Fífún Jèhófà Ní Ohun Tó Tọ́ Sí I (T. Vasiliou), 10/1
Jèhófà Jẹ́ Ọlọ́run Olóore sí Mi (J. Andronikos), 11/1
Jèhófà Ti Jẹ́ Àpáta Gàǹgà Mi (E. Lionoudakis), 9/1
Láti Inú Ipò Òṣì Paraku, Mo Bọ́ Sínú Ọrọ̀ (M. Almeida), 7/1
Mímú Ìlérí Mi Láti Sin Ọlọ́run Ṣẹ (F. Gudlikies), 6/1
Mò Ń Wá Párádísè Kiri (P. Stisi), 4/1
Ó Lé Lógójì Ọdún Táa Fi Wà Lábẹ́ Ìfòfindè (M. V. Savitskii), 3/1
Ó Ṣèrànwọ́ Láti Tan Ìmọ́lẹ̀ (L. Barry), 10/1
Yíyọ̀ Láìka Àwọn Àdánwò Sí (G. Scipio), 2/1
JÈHÓFÀ
A Mú Orúkọ Náà Padà Bọ̀ Sípò, 3/1
A Pe Orúkọ Àtọ̀runwá Náà ní Ísírẹ́lì, 7/1
“Jèhófà Fúnra Rẹ̀ Ní Ń Fúnni Ní Ọgbọ́n,” 11/15
Kò Fi Nǹkan Falẹ̀, 6/1
Ṣé “Jèhófà” Ni, Àbí “Yahweh”? 2/1
Ṣe Nǹkan Lọ́nà “Wíwọ́” Bí? 5/1
JÉSÙ KRISTI
Bí Jésù Ṣe Lè Yí Ìgbésí Ayé Rẹ Padà, 7/1
Ọjọ́ Tí Ó Lò Kẹ́yìn Gẹ́gẹ́ Bí Ènìyàn, 3/15
Ọkùnrin Títóbilọ́lá Jù Lọ Ṣe Iṣẹ́ Rírẹlẹ̀, 3/1
LÁJORÍ ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
Atóbilọ́lá Amọ̀kòkò Náà àti Iṣẹ́ Rẹ̀, 2/1
Àwọn Àǹfààní Tó Wà Nínú Nínífẹ̀ẹ́ Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run, 11/1
“Àwọn Ẹ̀bùn Tí Ó Jẹ́ Ènìyàn” Láti Máa Bójú Tó Àwọn Àgùntàn Jèhófà, 6/1
Báwo Lo Ṣe Nífẹ̀ẹ́ Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Tó? 11/1
“Ẹ Fìdí Ọkàn-Àyà Yín Múlẹ̀ Gbọn-in,” 1/1
“Ẹ Fi Ìrẹ̀lẹ̀ Èrò Inú Di Ara Yín Lámùrè,” 8/1
Ẹ Jẹ́ Ká Wà Lára Àwọn Tó Ní Ìgbàgbọ́, 12/15
Ẹlẹ́dàá Lè Mú Kí Ayé Rẹ Nítumọ̀, 6/15
Ẹ Máa Bọlá Fáwọn Ẹlòmíràn, 8/1
Ẹ Máa Dárí Jini Látọkàn Wá, 10/15
Ẹ Máa Gbé Ọwọ́ Ìdúróṣinṣin Sókè Nínú Àdúrà, 1/15
Ẹ Wà Lójúfò, Kí Ẹ Sì Jẹ́ Aláápọn! 5/1
Ẹ̀yin Ìdílé, Ẹ Máa Yin Ọlọ́run Gẹ́gẹ́ Bí Apá Kan Ìjọ Rẹ̀, 7/1
Ẹ̀yin Òbí, Ẹ̀kọ́ Wo Làpẹẹrẹ Yín Ń Kọ́ni? 7/1
Ẹ̀yin Ọ̀dọ́—Ẹ Dènà Ẹ̀mí Ayé, 9/1
Ẹ̀yin Ọ̀dọ́—Ẹ Kọ́ Agbára Ìwòye Yín! 9/1
“Fi Ọkàn-Àyà Rẹ Sí” Tẹ́ńpìlì Ọlọ́run! 3/1
Ìbùkún Jèhófà Lórí “Ilẹ̀” Wa, 3/1
“Ìgbà Àlàáfíà” Ti Fẹ́rẹ̀ẹ́ Dé! 10/1
Inú Wa Dùn Pé Jèhófà Ń Fọ̀nà Rẹ̀ Hàn Wá, 5/15
Ìràpadà Kristi—Ọ̀nà Tí Ọlọ́run Là Sílẹ̀ fún Ìgbàlà, 2/15
Ìrètí Ló Mú Wa Dúró, Ìfẹ́ Ló Ń Sún Wa Ṣiṣẹ́, 7/15
Ìṣúra Wa Ń Bẹ Nínú Ohun Èlò Tí A Fi Amọ̀ Ṣe, 2/1
Ìwàláàyè Lẹ́yìn Ikú—Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Rẹ̀? 4/1
Ìwàláàyè Lẹ́yìn Ikú—Kí Ni Ìgbàgbọ́ Àwọn Ènìyàn? 4/1
Ìyè Àìnípẹ̀kun Ha Ṣeé Ṣe Lóòótọ́ Bí? 4/15
Jèhófà Ń Ṣètò Sílẹ̀, 8/15
Jẹ́ Ẹni Tí Ń Fi Ayọ̀ Ka Ìwé Ìṣípayá, 12/1
Kẹ́sẹ Járí Nínú Ìgbésí Ayé Rẹ! 9/1
Kí A Má Ṣe Fà Sẹ́yìn sí Ìparun! 12/15
Kíkẹ́kọ̀ọ́ Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Déédéé Gẹ́gẹ́ Bí Ìdílé, 7/1
Kí Ni Jèhófà Ń Béèrè Lọ́wọ́ Wa Lónìí? 9/15
“Kí Òǹkàwé Lo Ìfòyemọ̀,” 5/1
“Làbárè Amúniyọ̀ṣẹ̀ṣẹ̀” Látinú Ìwé Ìṣípayá, 12/1
Lílo Ìgbàgbọ́ Nínú Àwọn Ìlérí Ọlọ́run, 8/15
Máa Fiyè sí Ẹ̀kọ́ Rẹ Nígbà Gbogbo, 3/15
Máa Lo Ìjìnlẹ̀ Òye àti Ìyíniléròpadà Tóo Bá Ń Kọ́ni, 3/15
Máa Rìn ní Ọ̀nà Jèhófà, 5/15
Mímọrírì “Àwọn Ẹ̀bùn Tí Ó Jẹ́ Ènìyàn,” 6/1
Mọ Irú Ẹni Tí Ẹlẹ́dàá Rẹ Jẹ́, 6/15
Ǹjẹ́ O Nígbàgbọ́ Bíi Ti Ábúráhámù? 1/1
Ǹjẹ́ Ò Ń Ṣe Gbogbo Ojúṣe Rẹ Níwájú Ọlọ́run? 11/15
“Nǹkan Wọ̀nyí Gbọ́dọ̀ Ṣẹ,” 5/1
O Ha ‘Ń Pèsè Àdúrà Rẹ Bíi Tùràrí’ Bí? 1/15
“Ohun Gbogbo Ni Ìgbà Tí A Yàn Kalẹ̀ Wà Fún,” 10/1
O Lè Fara Dà Á Dé Òpin, 10/1
O Lè Jèrè Arákùnrin Rẹ, 10/15
Ọ̀nà Ìfẹ́ Kì Í Kùnà, 2/15
Ọ̀nà Kan Ṣoṣo Tó Lọ sí Ìyè Àìnípẹ̀kun, 4/15
Rántí Ẹlẹ́dàá Rẹ Atóbilọ́lá! 11/15
Ríran Àwọn Ènìyàn Lọ́wọ́ Láti Sún Mọ́ Jèhófà, 7/15
Ṣé Ohun Tí Jèhófà Ń Béèrè Lọ́wọ́ Wa Pọ̀ Jù Ni? 9/15
“Tẹ́ńpìlì Náà” àti “Ìjòyè Náà” Lónìí, 3/1
Ọ̀KAN-Ò-JỌ̀KAN
Àkókò àti Ayérayé, 6/1
Àsọtẹ́lẹ̀ Inú Ìwé Ìṣípayá—Ṣé Ká Máa Bẹ̀rù Rẹ̀ Ni Àbí? 12/1
Àwọn Alábàáṣiṣẹ́pọ̀ Pọ́ọ̀lù, 6/1
Àwọn Àlọ́ Tí Ọlọ́run Mí Sí, 10/1
Àwọn Kọ́líjéètì, 4/15
Báwo La Ṣe Lè Pẹ́ Tó Láyé? 4/15
Èé Ṣe Tí Àkókò Fi Kéré Tó Bẹ́ẹ̀? 10/1
Èrè Ìgbéraga, 2/1
Ẹgbẹ̀rúndún Tó Ṣe Pàtàkì, 11/1
Ẹ̀mí Kẹ́lẹ́yàmẹ̀yà àti Ìsìn, 8/1
Ẹ̀tọ́ Ọgbọọgba, 8/1
Fílípì—Ajíhìnrere Tó Nítara, 7/15
Gbogbo Èèyàn Yóò Lómìnira, 5/1
Gbogbo Kìràkìtà Wa Láti Pẹ́ Láyé, 10/15
Ìjọsìn Báálì, 4/1
Ìmọ̀ Ọgbọ́n Gíríìkì—Ṣé Ó Ṣe Ẹ̀sìn Kristẹni Lóore? 8/15
Ìwà Bàsèjẹ́, 6/15
“Ìyálóde Aginjù Síríà Abirun-Dúdú Mìnìjọ̀” (Senobíà), 1/15
Ìyè Wù Ọ́, 8/15
“Iyọ̀ Pàdánù Okun Rẹ̀,” 8/15
Kérésìmesì ní Ìlà Oòrùn Ayé, 12/15
Lo Àkókò Pẹ̀lú Ìdílé Rẹ, 5/15
“Nínú Àwọn Ewu Odò,” 3/15
Ǹjẹ́ Ẹnikẹ́ni Tiẹ̀ Bìkítà? 9/15
Òfin Àtẹnudẹ́nu (Ìsìn Àwọn Júù), 1/15
Ojúlówó Ìrànwọ́ fún Ìdílé, 1/1
Òkè Athos—Ṣé “Òkè Mímọ́” Ni? 12/1
Ọdún 2000—Ṣọ́dún Abàmì Ni? 11/1
Rashi—Ògúnnágbòǹgbò Alálàyé Bíbélì, 3/15
Sílà—Orísun Ìṣírí, 2/15
Sọ́ọ̀lù (Pọ́ọ̀lù), 5/15, 6/15
Ṣé Èṣù Ló Ń Jẹ́ Ká Ṣàìsàn Ni? 9/1
Tímótì—“Ojúlówó Ọmọ Nínú Ìgbàgbọ́,” 9/15
Wọ́n Kọ́lé Sórí Ìpìlẹ̀ Àwọn Abọ̀rìṣà, 3/15
Wọ́n Ń Jà Nítorí Ibi “Mímọ́,” 2/15
WỌ́N ṢE ÌFẸ́ JÈHÓFÀ
Ìbẹ̀wò Kan Tó Lérè Púpọ̀ (Ọbabìnrin Ṣébà), 7/1
Ìdáríjì (Jósẹ́fù), 1/1
Màríà Yan “Ìpín Rere,” 9/1
Ọkùnrin Títóbilọ́lá Jù Lọ Ṣe Iṣẹ́ Rírẹlẹ̀ (Jésù), 3/1
Ọrẹ Àtinúwá Láti Gbé Ìjọsìn Mímọ́ Ga, 11/1
Pọ́ọ̀lù Borí Ìpọ́njú, 5/1