A7-G
Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Pàtàkì Nínú Ìgbésí Ayé Jésù—Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Tí Jésù Ṣe Kẹ́yìn ní Jerúsálẹ́mù (Apá Kìíní)
| ÀKÓKÒ | IBI | ÌṢẸ̀LẸ̀ | MÁTÍÙ | MÁÀKÙ | LÚÙKÙ | JÒHÁNÙ | 
|---|---|---|---|---|---|---|
| 33, Nísàn 8 | Bẹ́tánì | Jésù dé lọ́jọ́ mẹ́fà ṣáájú Ìrékọjá | ||||
| Nísàn 9 | Bẹ́tánì | Màríà da òróró sí orí àti ẹsẹ̀ rẹ̀ | ||||
| Bẹ́tánì sí Bẹtifágè sí Jerúsálẹ́mù | Ó wọ Jerúsálẹ́mù tiyì-tẹ̀yẹ, ó gun kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ | |||||
| Nísàn 10 | Bẹ́tánì sí Jerúsálẹ́mù | Ó gégùn-ún fún igi ọ̀pọ̀tọ́; ó fọ tẹ́ńpìlì mọ́ lẹ́ẹ̀kan sí i | ||||
| Jerúsálẹ́mù | Àwọn àlùfáà àgbà àtàwọn akọ̀wé òfin gbìmọ̀ pọ̀ láti pa Jésù | |||||
| Jèhófà sọ̀rọ̀; Jésù sọ àsọtẹ́lẹ̀ nípa ikú rẹ̀; àsọtẹ́lẹ̀ tí Àìsáyà sọ nípa àìnígbàgbọ́ àwọn Júù ṣẹ | ||||||
| Nísàn 11 | Bẹ́tánì sí Jerúsálẹ́mù | Ẹ̀kọ́ látara igi ọ̀pọ̀tọ́ tó rọ | ||||
| Jerúsálẹ́mù, tẹ́ńpìlì | Wọ́n béèrè ẹni tó fún Jésù láṣẹ; àpèjúwe ọmọkùnrin méjì | |||||
| Àwọn àpèjúwe: àwọn tó ń dáko tí wọ́n jẹ́ apààyàn, àsè ìgbéyàwó | ||||||
| Ó dáhùn ìbéèrè nípa Ọlọ́run àti Késárì, àjíǹde, àṣẹ tó tóbi jù lọ | ||||||
| Ó bi àwọn èrò bóyá Kristi jẹ́ ọmọ Dáfídì | ||||||
| Àwọn akọ̀wé òfin àtàwọn Farisí gbé | ||||||
| Ó kíyè sí ohun tí opó kan fi ṣètọrẹ | ||||||
| Òkè Ólífì | Ó sọ àmì ìgbà tí òun máa wà níhìn-ín | |||||
| Àwọn àpèjúwe: wúńdíá mẹ́wàá, tálẹ́ńtì, àgùntàn àti ewúrẹ́ | ||||||
| Nísàn 12 | Jerúsálẹ́mù | Àwọn aṣáájú Júù gbìmọ̀ pọ̀ láti pa á | ||||
| Júdásì ṣètò bó ṣe máa fà á lé wọn lọ́wọ́ | ||||||
| Nísàn 13 (Ọ̀sán Thursday) | Nítòsí àti nínú Jerúsálẹ́mù | Ó múra sílẹ̀ fún Ìrékọjá tó ṣe kẹ́yìn | ||||
| Nísàn 14 | Jerúsálẹ́mù | Ó bá àwọn àpọ́sítélì jẹ Ìrékọjá | ||||
| Ó fọ ẹsẹ̀ àwọn àpọ́sítélì |