ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 29:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 ‘Bí mo ṣe darí yín jálẹ̀ ogójì (40) ọdún nínú aginjù,+ aṣọ yín ò gbó mọ́ yín lára, bàtà yín ò sì gbó mọ́ yín lẹ́sẹ̀.+

  • Nehemáyà 9:21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 Ogójì (40) ọdún lo fi pèsè oúnjẹ fún wọn ní aginjù.+ Wọn ò ṣaláìní nǹkan kan. Aṣọ wọn ò gbó,+ ẹsẹ̀ wọn ò sì wú.

  • Sáàmù 23:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 23 Jèhófà ni Olùṣọ́ Àgùntàn mi.+

      Èmi kì yóò ṣaláìní.+

  • Sáàmù 34:9, 10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  9 Ẹ bẹ̀rù Jèhófà, gbogbo ẹ̀yin ẹni mímọ́ rẹ̀,

      Nítorí àwọn tó bẹ̀rù rẹ̀ kò ní ṣaláìní.+

      כ [Káfì]

      10 Bó tilẹ̀ jẹ́ pé ebi máa ń pa àwọn ọmọ kìnnìún* tó lágbára,

      Àmọ́ ní ti àwọn tó ń wá Jèhófà, wọn kò ní ṣaláìní ohun rere.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́