ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Kíróníkà 7:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 tí àwọn èèyàn mi tí à ń fi orúkọ mi pè+ sì rẹ ara wọn sílẹ̀,+ tí wọ́n gbàdúrà, tí wọ́n wá ojú mi, tí wọ́n sì kúrò nínú àwọn ọ̀nà búburú wọn,+ nígbà náà, màá gbọ́ láti ọ̀run, màá dárí ẹ̀ṣẹ̀ wọn jì wọ́n, màá sì wo ilẹ̀ wọn sàn.+

  • Jeremáyà 29:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 “Ohun tí Jèhófà sọ nìyí, ‘Tó bá ti pé àádọ́rin (70) ọdún tí ẹ ti wà ní Bábílónì, màá yí ojú mi sí yín,+ màá sì mú ìlérí mi ṣẹ láti mú yín pa dà wá sí ibí yìí.’+

  • Jeremáyà 29:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Ẹ ó pè mí, ẹ ó sì wá gbàdúrà sí mi, màá sì fetí sí yín.’+

  • Jeremáyà 50:4, 5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 “Ní àwọn ọjọ́ yẹn àti ní àkókò yẹn,” ni Jèhófà wí, “àwọn èèyàn Ísírẹ́lì àti àwọn èèyàn Júdà máa kóra jọ.+ Wọ́n á máa sunkún bí wọ́n ṣe ń rìn lọ,+ wọ́n á sì jọ máa wá Jèhófà Ọlọ́run wọn.+ 5 Wọ́n á béèrè ọ̀nà tó lọ sí Síónì, wọ́n á yíjú sí apá ibẹ̀,+ wọ́n á ní, ‘Ẹ wá, ẹ jẹ́ kí a bá Jèhófà dá májẹ̀mú tó máa wà títí láé, tí kò sì ní ṣeé gbàgbé.’+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́