-
Jóòbù 5:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Ó ń rọ òjò sí ayé,
Ó sì ń bomi rin oko.
-
-
Jóòbù 26:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Ó wé omi mọ́ inú àwọsánmà* rẹ̀,+
Débi pé àwọsánmà ò bẹ́, bí wọ́n tiẹ̀ wúwo;
-
Àìsáyà 40:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Ta ló ti kó gbogbo erùpẹ̀ ilẹ̀ sínú òṣùwọ̀n,+
Tàbí tó ti wọn àwọn òkè ńlá lórí ìwọ̀n,
Tó sì ti wọn àwọn òkè kéékèèké lórí òṣùwọ̀n?
-
-
-