Jẹ́nẹ́sísì 3:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Obìnrin náà wá rí i pé èso igi náà dára fún jíjẹ, ó dùn-ún wò, àní, igi náà wuni. Ló bá mú lára èso rẹ̀, ó sì jẹ ẹ́.+ Lẹ́yìn náà, ó fún ọkọ rẹ̀ lára èso náà nígbà tó wà lọ́dọ̀ rẹ̀, òun náà sì jẹ ẹ́.+ Jẹ́nẹ́sísì 6:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ọlọ́run wo ayé, àní ó ti bà jẹ́;+ ìwà ìbàjẹ́ ni gbogbo ẹlẹ́ran ara* ń hù ní ayé.+ Diutarónómì 32:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Àwọn ló hùwà ìbàjẹ́.+ Wọn kì í ṣe ọmọ rẹ̀, àwọn ló kan àbùkù.+ Ìran alárèékérekè àti oníbékebèke ni wọ́n!+
6 Obìnrin náà wá rí i pé èso igi náà dára fún jíjẹ, ó dùn-ún wò, àní, igi náà wuni. Ló bá mú lára èso rẹ̀, ó sì jẹ ẹ́.+ Lẹ́yìn náà, ó fún ọkọ rẹ̀ lára èso náà nígbà tó wà lọ́dọ̀ rẹ̀, òun náà sì jẹ ẹ́.+
5 Àwọn ló hùwà ìbàjẹ́.+ Wọn kì í ṣe ọmọ rẹ̀, àwọn ló kan àbùkù.+ Ìran alárèékérekè àti oníbékebèke ni wọ́n!+