ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 43:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  9 Kí gbogbo orílẹ̀-èdè pé jọ síbì kan,

      Kí àwọn èèyàn sì kóra jọ.+

      Èwo nínú wọn ló lè sọ èyí?

      Àbí wọ́n lè mú ká gbọ́ àwọn ohun àkọ́kọ́?*+

      Kí wọ́n mú àwọn ẹlẹ́rìí wọn wá, kí wọ́n lè fi hàn pé àwọn jàre,

      Tàbí kí wọ́n gbọ́, kí wọ́n sì sọ pé, ‘Òótọ́ ni!’”+

  • Àìsáyà 44:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  7 Ta ló dà bí èmi?+

      Kó pè, kó sọ ọ́, kó sì fi ẹ̀rí hàn mí!+

      Látìgbà tí mo ti gbé àwọn èèyàn àtijọ́ kalẹ̀,

      Jẹ́ kí wọ́n sọ àwọn ohun tó ń bọ̀

      Àti ohun tí kò tíì ṣẹlẹ̀.

  • Àìsáyà 45:21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 Ẹ sọ tẹnu yín, ẹ ro ẹjọ́ yín.

      Kí wọ́n fikùn lukùn ní ìṣọ̀kan.

      Ta ló ti sọ èyí tipẹ́tipẹ́,

      Tó sì kéde rẹ̀ láti ìgbà àtijọ́?

      Ṣebí èmi, Jèhófà ni?

      Kò sí Ọlọ́run míì, àfi èmi;

      Ọlọ́run òdodo àti Olùgbàlà,+ kò sí ẹlòmíì yàtọ̀ sí mi.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́