Jeremáyà 6:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 “Látorí ẹni kékeré títí dórí ẹni ńlá, kálukú wọn ń jẹ èrè tí kò tọ́;+Látorí wòlíì títí dórí àlùfáà, kálukú wọn ń lu jìbìtì.+ Jeremáyà 8:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Torí náà, màá fi ìyàwó wọn fún àwọn ọkùnrin míì,Màá fi oko wọn fún àwọn tó máa gbà á;+Látorí ẹni kékeré títí dórí ẹni ńlá, kálukú wọn ń jẹ èrè tí kò tọ́;+Látorí wòlíì títí dórí àlùfáà, kálukú wọn ń lu jìbìtì.+
13 “Látorí ẹni kékeré títí dórí ẹni ńlá, kálukú wọn ń jẹ èrè tí kò tọ́;+Látorí wòlíì títí dórí àlùfáà, kálukú wọn ń lu jìbìtì.+
10 Torí náà, màá fi ìyàwó wọn fún àwọn ọkùnrin míì,Màá fi oko wọn fún àwọn tó máa gbà á;+Látorí ẹni kékeré títí dórí ẹni ńlá, kálukú wọn ń jẹ èrè tí kò tọ́;+Látorí wòlíì títí dórí àlùfáà, kálukú wọn ń lu jìbìtì.+